on the island
where seabirds summer —
prison walls

 

l'órí erékùsù
tí àwọn ẹyẹ òkun ti ń lò'gbà
ọgbà ẹ̀wọ̀n

Cattails, April 2017 Issue