savannah fire . . .
a gazelle escapes
into an ambush

 

iná pápá . . .
ẹtu kan sá àsálà lọ sọ́wọ́
ọdẹ t'ó gẹ̀gùn

*Co-authored with my Dad, James O. Adeleke
Editor's Choice Haiku, Cattails, September 2016 Issue