after the muezzin's call
a market din turns off
shed by shed

 

lẹ́yìn ìrun pípè
ariwo ọjà kú
ní ìsọ̀ ní ìsọ̀

Heron's Nest, Volume XVIII, Number 2: June 2016