river ripples
the man I am keeps
staring at me

 

ojú omi ti dàrú
irú ọkùnrin tí mo jẹ́
sì ń wò mí

A Hundred Gourds 5:1 December 2015